Matiu 22:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Jesu tún fi òwe bá wọn sọ̀rọ̀. Ó ní,

2. “Ìjọba ọ̀run dàbí ọba kan, tí ó ń gbeyawo fún ọmọ rẹ̀.

3. Ó rán àwọn ẹrú rẹ̀ lọ pe àwọn tí ó dájọ́ igbeyawo náà fún, ṣugbọn wọn kò fẹ́ wá.

Matiu 22