Matiu 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀pọ̀ ninu àwọn eniyan tẹ́ aṣọ wọn sọ́nà; àwọn mìíràn ya ẹ̀ka igi, wọ́n tẹ́ wọn sọ́nà.

Matiu 21

Matiu 21:1-11