Matiu 21:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn alágbàro náà mú àwọn ẹrú rẹ̀, wọ́n na àwọn kan, wọ́n pa àwọn kan, wọ́n sọ àwọn mìíràn ní òkúta.

Matiu 21

Matiu 21:27-43