Matiu 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí a bá sì wí pé, ‘Láti ọ̀dọ̀ eniyan ni,’ a bẹ̀rù àwọn eniyan, nítorí gbogbo eniyan gbà pé wolii tòótọ́ ni Johanu.”

Matiu 21

Matiu 21:17-27