Matiu 21:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu wọ Jerusalẹmu, gbogbo ìlú mì tìtì. Àwọn ará ìlú ń bèèrè pé, “Ta nìyí?”

Matiu 21

Matiu 21:2-16