Matiu 20:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti ń jáde kúrò ní Jẹriko, ọ̀pọ̀ eniyan tẹ̀lé e.

Matiu 20

Matiu 20:22-33