Matiu 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dáhùn pé, “Ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀ ń bèèrè. Ẹ lè mu ninu ife ìrora tí èmi yóo mu?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “A lè mu ún.”

Matiu 20

Matiu 20:19-23