Matiu 20:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àbí n kò ní ẹ̀tọ́ láti ṣe ohun ìní mi bí mo ti fẹ́? Ṣé ò ń jowú nítorí mo ní inú rere ni?’

Matiu 20

Matiu 20:10-19