Matiu 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“A gbọ́ ohùn kan ní Rama,ẹkún ati ọ̀fọ̀ gidi.Rakẹli ń sunkún nítorí àwọn ọmọ rẹ̀;ó kọ̀, kò gba ìpẹ̀,nítorí wọn kò sí mọ́.”

Matiu 2

Matiu 2:17-21