Matiu 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Nítorí líle ọkàn yín ni Mose fi gbà fun yín láti kọ aya yín sílẹ̀. Ní ìbẹ̀rẹ̀ kò rí bẹ́ẹ̀.

Matiu 19

Matiu 19:3-14