Matiu 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni pé wọn kì í tún ṣe ẹni meji mọ́, bíkòṣe ọ̀kan. Nítorí náà ohun tí Ọlọrun bá ti so pọ̀, eniyan kò gbọdọ̀ yà á.”

Matiu 19

Matiu 19:1-15