Matiu 19:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wò wọ́n lójú, ó sọ fún wọn pé, “Èyí kò ṣeéṣe fún eniyan; ṣugbọn ohun gbogbo ni ó ṣeéṣe fún Ọlọrun.”

Matiu 19

Matiu 19:18-30