Matiu 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu sọ pé, “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọde wá sọ́dọ̀ mi; ẹ má dí wọn lọ́nà, nítorí ti irú wọn ni ìjọba ọ̀run.”

Matiu 19

Matiu 19:6-23