Matiu 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó sọ fún wọn pé, “Kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó lè gba nǹkan yìí, àfi àwọn tí Ọlọrun bá fi fún láti gbà á.

Matiu 19

Matiu 19:2-16