Matiu 18:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Olówó ẹrú náà bá pè é, ó sọ fún un pé, ‘Ìwọ ẹrú burúkú yìí! Mo bùn ọ́ ní adúrú gbèsè nnì nítorí o bẹ̀ mí.

Matiu 18

Matiu 18:30-35