Matiu 18:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹrú, ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ bá dọ̀bálẹ̀, ó ń bẹ̀ ẹ́ pé, ‘Ṣe sùúrù fún mi, n óo san án fún ọ.’

Matiu 18

Matiu 18:25-35