Matiu 18:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹrú náà bá dọ̀bálẹ̀, ó bẹ olówó rẹ̀ pé, ‘Ṣe sùúrù fún mi, n óo san gbogbo gbèsè mi fún ọ.’

Matiu 18

Matiu 18:18-27