Matiu 18:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ gan-an ni, kì í ṣe ìfẹ́ Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run pé kí ọ̀kan ninu àwọn kékeré wọnyi kí ó ṣègbé.

Matiu 18

Matiu 18:5-15