Matiu 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ mẹfa, Jesu mú Peteru ati Jakọbu ati Johanu arakunrin Jakọbu, wọ́n lọ sí orí òkè gíga kan; àwọn nìkan wà níbẹ̀.

Matiu 17

Matiu 17:1-4