Matiu 16:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Jesu wá pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni pé òun ni Mesaya.

Matiu 16

Matiu 16:15-25