Matiu 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá wọn lóhùn pé, “Nígbà tí ọjọ́ bá rọ̀, ẹ máa ń sọ pé, ‘Ojú ọjọ́ dára, nítorí ojú ọ̀run pupa.’

Matiu 16

Matiu 16:1-5