Matiu 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Kí ló dé tí ẹ̀yin náà ṣe ń fi àṣà ìbílẹ̀ yín rú òfin Ọlọrun?

Matiu 15

Matiu 15:1-7