Matiu 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ye yín pé ikùn ni gbogbo ohun tí eniyan bá fi sí ẹnu ń lọ ati pé eniyan óo tún yà á jáde?

Matiu 15

Matiu 15:7-25