Matiu 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dun ọba, ṣugbọn nítorí pé ó ti búra, ati nítorí àwọn tí ó wà níbi àsè, ó gbà láti fi fún un.

Matiu 14

Matiu 14:8-15