Matiu 14:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ó rí i tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́, ẹ̀rù bà á, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí rì. Ó bá kígbe pé, “Oluwa, gbà mí!”

Matiu 14

Matiu 14:27-36