Matiu 13:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olódodo yóo wá máa ràn bí oòrùn ninu ìjọba Baba wọn. Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́ràn, kí ó gbọ́.

Matiu 13

Matiu 13:34-46