Matiu 13:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, bí wọn tíí kó èpò jọ tí wọn ń sun ún ninu iná, bẹ́ẹ̀ ni yóo rí ní ìgbẹ̀yìn ayé.

Matiu 13

Matiu 13:30-48