Matiu 13:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá wọn lóhùn pé, ‘Ọ̀tá ni ó ṣe èyí.’ Àwọn ẹrú rẹ̀ ní, ‘Ṣé kí á lọ tu wọ́n dànù?’

Matiu 13

Matiu 13:26-34