Matiu 13:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún pa òwe mìíràn fún wọn. Ó ní, “Bí ìjọba ọ̀run ti rí nìyí. Ó dàbí ọkunrin kan tí ó gbin irúgbìn rere sí oko rẹ̀.

Matiu 13

Matiu 13:14-28