Matiu 12:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe ìfẹ́ Baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run, òun ni arakunrin mi ati arabinrin mi ati ìyá mi.”

Matiu 12

Matiu 12:40-50