Matiu 12:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹni tí kò bá ṣe tèmi, ó lòdì sí mi. Ẹni tí kò bá máa bá mi kó nǹkan jọ, ó ń fọ́nká ni.

Matiu 12

Matiu 12:22-40