Matiu 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu mọ̀ bẹ́ẹ̀, ó bá kúrò níbẹ̀. Ọpọlọpọ eniyan sì tẹ̀lé e, ó sì wo gbogbo wọn sàn.

Matiu 12

Matiu 12:13-21