Matiu 12:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sọ fún ọkunrin náà pé, “Na ọwọ́ rẹ.”Ó bá nà án. Ọwọ́ rẹ̀ bá bọ́ sípò gẹ́gẹ́ bí ekeji.

Matiu 12

Matiu 12:11-14