Matiu 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ni ẹ jáde lọ wò? Wolii ni bí? Bẹ́ẹ̀ ni. Mo sọ fun yín, ó tilẹ̀ ju wolii lọ.

Matiu 11

Matiu 11:2-14