Matiu 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ẹ lọ ròyìn ohun tí ẹ ti gbọ́ ati ohun tí ẹ ti rí fún Johanu. Ẹ sọ fún un pé,

Matiu 11

Matiu 11:1-5