Matiu 11:29-30 BIBELI MIMỌ (BM)

29. Ẹ gba àjàgà mi sí ọrùn yín, kí ẹ sì wá kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ mi, nítorí onírẹ̀lẹ̀ ati ọlọ́kàn tútù ni mí, ọkàn yín yóo sì balẹ̀.

30. Nítorí àjàgà mi tuni lára, ẹrù mi sì fúyẹ́.”

Matiu 11