Matiu 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí ni ǹ bá fi ìran yìí wé? Ó dàbí àwọn ọmọde tí wọ́n jókòó ní ọjà, tí wọn ń ké sí àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn pé.

Matiu 11

Matiu 11:9-22