Matiu 10:40 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹni tí ó bá gbà yín, èmi ni ó gbà. Ẹni tí ó bá sì gbà mí, ó gba ẹni tí ó fi iṣẹ́ rán mi.

Matiu 10

Matiu 10:39-42