Matiu 10:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ má bẹ̀rù àwọn eniyan. Kò sí ohun tí ó wà ní ìpamọ́, tí kò ní fara hàn. Kò sì sí ohun àṣírí tí a kò ní mọ̀.

Matiu 10

Matiu 10:20-27