Matiu 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo eniyan ni yóo kórìíra yín nítorí orúkọ mi. Ṣugbọn ẹni tí ó bá fara dà á títí dé òpin, òun ni a óo gbà là.

Matiu 10

Matiu 10:13-23