Matiu 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Josẹfu jí láti ojú oorun, ó ṣe gẹ́gẹ́ bí angẹli Oluwa náà ti pàṣẹ fún un. Ó mú iyawo rẹ̀ sọ́dọ̀.

Matiu 1

Matiu 1:23-25