Matiu 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo bí ọmọkunrin kan, o óo sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jesu nítorí òun ni yóo gba àwọn eniyan rẹ̀ là kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”

Matiu 1

Matiu 1:12-25