Matiu 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọn kó wọn lẹ́rú lọ sí Babiloni, Jekonaya bí Ṣealitieli, Ṣealitieli bí Serubabeli.

Matiu 1

Matiu 1:9-22