Maku 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àánú àwọn eniyan wọnyi ń ṣe mí, nítorí ó di ọjọ́ mẹta tí wọ́n ti wà pẹlu mi, wọn kò ní ohun tí wọn yóo jẹ mọ́.

Maku 8

Maku 8:1-3