Maku 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá kìlọ̀ fún wọn pé, “Ẹ kíyèsára kí ẹ sì ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisi ati ìwúkàrà Hẹrọdu.”

Maku 8

Maku 8:14-23