Maku 7:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbé ojú sí òkè ọ̀run, ó kẹ́dùn, ó bá ní, “Efata,” ìtumọ̀ èyí tí i ṣe, “Ìwọ, ṣí.”

Maku 7

Maku 7:30-36