Maku 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu wí fún wọn pé, “Kò sí wolii tí kò níyì, àfi ní ìlú ara rẹ̀, ati láàrin àwọn ará rẹ̀, ati ninu ẹbí rẹ̀.”

Maku 6

Maku 6:2-12