Maku 6:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá fi àwo pẹrẹsẹ gbé orí rẹ̀ wá, ó fi í fún ọmọbinrin náà. Ọmọbinrin náà bá gbé e lọ fún ìyá rẹ̀.

Maku 6

Maku 6:19-31