Maku 6:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú ọba bàjẹ́ pupọ, ṣugbọn nítorí ó ti ṣe ìlérí pẹlu ìbúra lójú àwọn tí ó wà níbi àsè, kò fẹ́ kọ̀ fún un.

Maku 6

Maku 6:23-34