Maku 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila ti ń lọ, wọ́n ń waasu pé kí gbogbo eniyan ronupiwada.

Maku 6

Maku 6:5-22